Sáàmù 136:7-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

7. Fún ẹni tí ó dá àwọn ìmọ́lẹ̀ ńlá;nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé

8. Òòrùn láti jọba ọ̀sán;nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

9. Òsùpá àti ìràwọ̀ láti jọba òru;nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

Sáàmù 136