Sáàmù 135:15-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Sílífà Òun wúrà ní èrè àwọn aláìkọlà,iṣẹ́ ọwọ́ ènìyàn.

16. Wọn ní ẹnu, ṣùgbọ́n wọ́n kò sọ̀rọ;wọn ní ojú, ṣùgbọ́n wọn kò fi ríran.

17. Wọ́n ní etí, ṣùgbọ́n wọn kò fi gbọ́ràn;bẹ́ẹ̀ ni kò si èèmí kan ní ẹnu wọn

18. Àwọn tí ó ṣe wọn dàbí wọn:bẹ́ẹ̀ sì ní olúkùlùkù ẹni tí ó gbẹ́kẹ̀lé wọn.

19. Ẹ̀yin ara ilé Ísírẹ́lì, ẹ fi ìbùkún fún Olúwa,ẹ̀yin ará ilé Árónì, fi ìbùkún fún Olúwa.

20. Ẹ̀yin ará ilé Léfì, fi ìbùkún fún Olúwa;ẹ̀yin tí ó bẹ̀rù Olúwa, fi ìbùkún fún Olúwa.

Sáàmù 135