Sáàmù 133:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Kíyèsí, ó ti dára ó sì ti dùn tó fúnàwọn ará láti máa jùmọ̀ gbé ní ìrẹ́pọ̀.

2. Ó dàbí òróró ìkúnra iyebíye ní orí,tí ó ṣàn dé irungbọ̀n, àní irungbọ̀n Árónì:tí ó sì ṣàn sí etí aṣọ sórí Rẹ̀;

Sáàmù 133