Sáàmù 132:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa, rántí Dáfídìnínú gbogbo ìpọ́njú Rẹ̀:

2. Ẹni tí ó ti búra fún Olúwa,tí ó sì ṣe ìlèrí fún Alágbára Jákọ́bù pé.

Sáàmù 132