Sáàmù 13:4-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Ọ̀tá mi wí pé, “Èmi ti ṣẹ́gun Rẹ̀,”àwọn ọ̀ta mi yóò yọ̀ tí mo bá ṣubú.

5. Ṣùgbọ́n mo gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ Rẹ tí kì í kùnà;ọkàn mi ń yọ̀ nínú ìgbàlà Rẹ.

6. Èmi ó kọrin sí Olúwa,nítorí ó dára sí mi.

Sáàmù 13