Sáàmù 129:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójúláti ìgbà èwe mi wá ni kíÍsírẹ́lì kí ó wí nísinsinyí

2. Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójúláti ìgbà èwe mi wá;ṣíbẹ̀ wọn kò tíì borí mi.

3. Àwọn awalẹ̀ walẹ̀ sí ẹ̀yìn mi:wọ́n sì là aporo wọn gígùn.

4. Olódodo ní Olúwa:ó ti ké okùn àwọn ènìyàn búburú kúrò.

Sáàmù 129