Sáàmù 127:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Bí kò ṣè pé Olúwa bá kọ́ ile náààwọn tí n kọ ọ ńṣiṣẹ́ lásán ni;bí kò sé pé Olúwa bá pa ilú mọ́, olùṣọ́ jí lásán.

2. Asán ni fún ẹ̀yin ti ẹ dìde ní kùtùkùtùlati pẹ́ dùbúlẹ̀, láti jẹ oúnjẹ́ làálàá;bẹ́ẹ̀ ni ó ń fi ire fún olùfẹ́ Rẹ̀ lójú ọ̀run.

Sáàmù 127