Sáàmù 125:4-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Olúwa ṣe rere fún àwọn ẹni rere,àti fún àwọn tí àyà wọn dúró ṣinṣin.

5. Bí ó ṣe ti irú àwọn tí wọn yà sí ipa ọ̀nà wíwọ́ wọn; Olúwa yóò jẹ́ kí wọn lọ pẹ̀lú àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀.Ṣùgbọ́n àlàáfíà yóò wà lórí Ísírẹ́lì.

Sáàmù 125