Sáàmù 124:7-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

7. Ọkàn wa yọ bí ẹyẹ jáde kúrò nínú okùn apẹyẹ;okùn já àwa sì yọ.

8. Ìrànlọ́wọ́ wa ń bẹ ní orúkọ Olúwa,tí ó dá ọ̀run òun ayé.

Sáàmù 124