Sáàmù 123:3-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Olúwa, ṣàánú fún wa, ṣàánú fún wa;nítorí tí a kún fún ẹ̀gàn púpọ̀ púpọ̀.

4. Ọkàn wa kún púpọ̀ fún ẹ̀gàn àwọn onírera,àti fún ẹ̀gàn àwọn agbéraga.

Sáàmù 123