Sáàmù 123:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ìwọ ní mo gbé ojú mí sókè sí,ìwọ tí ń gbé inú ọ̀run

2. Kíyèsí, bí ojú àwọnìránṣẹ́ kùnrin ti máa ń wo ọwọ́ àwọn baba wọn,àti bí ojú ìránṣẹ́-bìnrin ti máa ń wo ọwọ́ ìyá Rẹ̀bẹ́ẹ̀ ni ojú wa ń wo Olúwa Ọlọ́run wa,títí yóò fi ṣàánú fún wa.

Sáàmù 123