Sáàmù 122:6-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Gbàdúrà fún àlàáfíà Jérúsálẹ́mù;àwọn tí o fẹ́ ọ yóò ṣe rere.

7. Kí àlàáfíà kí ó wà nínú odi Rẹ̀,àti ire nínú ààfin Rẹ̀.

8. Nítorí àwọn ọkùnrin àti àwọn ẹgbẹ́ mièmi yóò wí nísinsìyí pé,kí àlàáfíà kí ó wà nínú Rẹ̀;

9. Nítorí ilé Olúwa Ọlọ́run wa,èmi yóò máa wá ire Rẹ̀.

Sáàmù 122