Sáàmù 121:4-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Kíyèsí, ẹni tí ń pa Ísírẹ́lì mọ́,kì í tòògbé bẹ́ẹ̀ ni kì í sùn.

5. Olúwa ni olùpamọ́ Rẹ; Olúwa ní òjìji Rẹ ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹ

6. Oòrùn kì yóò pa ọ ní ìgbà ọ̀sántàbí òṣùpá ní ìgbà òru.

7. Olúwa yóò pa ọ́ mọ́ kúrò nínú ibi gbogboyóò pa ọkàn Rẹ mọ́

Sáàmù 121