Sáàmù 120:6-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY) Ó ti pẹ́ tí èmi ti ń gbéláàrin àwọn tí ó kóríra àlàáfíà.