Sáàmù 119:98 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àṣẹ Rẹ mú mi gbọ́n ju àwọn ọ̀ta mi lọ,nítorí wọ́n wà pẹ̀lú mi láé.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:91-99