Sáàmù 119:81 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn mi ń fojú sọ́nà nítorí ìgbàlà Rẹ,ṣùgbọ́n èmi tí mú ìrètí mi sínú ọ̀rọ̀ Rẹ.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:72-89