Sáàmù 119:63-66 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

63. Èmi jẹ́ ọ̀rẹ́ sí gbogbo àwọn tí ó bẹ̀rù Rẹ,sí gbogbo àwọn tí ń tẹ̀lé ẹ̀kọ́ Rẹ̀.

64. Ayé kún fún ìfẹ́ Rẹ OlúwaKọ́ mi ní òfin Rẹ.

65. Ṣe rere sí ìránṣẹ́ Rẹgẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Rẹ, Olúwa.

66. Kọ́ mi ni ìmọ̀ àti ìdájọ́ rere,nítorí mo gbàgbọ́ nínú àṣẹ Rẹ.

Sáàmù 119