Sáàmù 119:51-54 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

51. Àwọn agbéraga fi mi ṣe ẹlẹ́yà láì dádúró,ṣùgbọ́n èmi kò padà nínú òfin Rẹ.

52. Èmi rántí àwọn òfin Rẹ ìgbàanì, Olúwa,èmi sì rí ìtùnú nínú wọn.

53. Ìbínú dìmí mú ṣinṣin nítorí àwọn ẹni búburútí wọ́n ti kọ òfin Rẹ sílẹ̀.

54. Òfin Rẹ ni ọ̀rọ̀ ìpìlẹ̀ orin miníbikíbi tí èmi ń gbé.

Sáàmù 119