Sáàmù 119:5-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Ọ̀nà mi ìbá dúró ṣinṣinláti máa pa òfin Rẹ̀ mọ́!

6. Nígbà náà, ojú kò ní tì mínígbà tí mo bá ń kíyèsí àṣẹ Rẹ̀ gbogbo.

7. Èmi yóò yìn ọ́ pẹ̀lú ọkàn ìdúró ṣinṣinbí èmi bá ti kọ́ òfin òdodo Rẹ̀.

8. Èmi yóò gbọ́ràn sí asẹ Rẹ̀:Má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀ pátapáta.

9. Báwo ni àwọn èwe ènìyàn yóò ti ṣe pa ọ̀nà Rẹ̀ mọ́?Láti máa gbé ní ìbámu sí ọ̀rọ̀ Rẹ.

Sáàmù 119