Sáàmù 119:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni èmi yóò dáẹni tí ń sọ̀rọ̀ ẹ̀gàn sí mi lóhùn,nítorí èmi gbẹ́kẹ̀lé ọ̀rọ̀ Rẹ.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:35-47