Sáàmù 119:36-40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

36. Yí ọkàn mi padà sí òfin Rẹ̀kí ó má ṣe sí ojú kòkòrò mọ́.

37. Yí ojú mi padà kúrò láti máa wo ohun asán:pa ayé mí mọ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Rẹ.

38. Mú ìlérí Rẹ sẹ sí ìránṣẹ́ Rẹ,nítorí òfin Rẹ dára.

39. Yí ẹ̀gàn mi padà tí mo bẹ̀rùni torí tí idájọ́ Rẹ dára.

40. Kíyèsíi ọkàn mi ti fà sí ẹ̀kọ́ Rẹ!Pa ayé mí mọ́ nínú òdodo Rẹ.

Sáàmù 119