Sáàmù 119:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kọ́ mi, Olúwa, láti tẹ̀lé àṣẹ Rẹ;nígbà náà ni èmi yóò pa wọ́n mọ́ dé òpin.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:24-40