Sáàmù 119:175-176 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

175. Jẹ́ kí èmi wà láàyè ki èmi lè yìn ọ́,kí o sì jẹ́ kí òfin Rẹ mú mi dúró.

176. Èmí ti sìnà bí àgùntàn tí ósọnùú wá ìránṣẹ́ Rẹ,nítorí èmi kò gbàgbé àṣẹ Rẹ.

Sáàmù 119