Sáàmù 119:169 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí igbe mi wá sí iwájú Rẹ, Olúwa;fún mi ní òye gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Rẹ.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:162-173