Sáàmù 119:128 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí èmi kíyèsí gbogbo ẹ̀kọ́ òtítọ́ Rẹ̀,èmi kórìíra gbogbo ipa ọ̀nà búburú.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:125-135