Sáàmù 119:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ìbùkún ni fún àwọn ẹni tí ọ̀nà wọn wà láìlẹ́sẹ̀,ẹni tí í rìn ní ìbámu pẹ̀lú òfin Olúwa,

2. Ìbùkún ni fún àwọn ẹni tí ń pa òfin Rẹ̀ mọ́tí wọn sì ń wá a pẹ̀lú gbogbo ọkàn wọn.

Sáàmù 119