Sáàmù 115:17-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

17. Òkú kò le yìn Olúwa,tàbí ẹni tí o ti lọ sí ìṣàlẹ̀ ìdákẹ́jẹ́.

18. Ṣùgbọ́n àwa o fi ìbùkún fún Olúwaláti ìsinsìn yí lọ àti títí láéláé.Ẹ yin Olúwa.

Sáàmù 115