Sáàmù 114:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nígbà tí Ísírẹ́lì jáde ní Éjíbítì,ilé Jákọ́bù láti inú ènìyàn àjòjì èdè

2. Júdà wà ní ibi mímọ́,Ísírẹ́lì wà ní ìjọba.

Sáàmù 114