Sáàmù 113:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ máa yin Olúwa, yìn ín ẹ̀yin ìránṣẹ́ Olúwa,ẹ yin orúkọ Olúwa.

2. Fi ìbùkún fún orúkọ Olúwa látiìsinsin yìí lọ àti títí láéláé.

3. Láti ìlà òòrun títí dé ìwọ Rẹ̀orúkọ Olúwa ni kí á máa yìn.

Sáàmù 113