Sáàmù 111:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ máa yin Olúwa. Èmi yóò máayìn Olúwa pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi,ní àwujọ àwọn olóòtọ́, àti ní ijọ ènìyàn.

2. Iṣẹ́ Olúwa tóbi, àwọn tí ó ní inú dídùn, ń ṣe àṣàrò nínú Rẹ̀.

3. Iṣẹ́ Rẹ̀ ní ọlá ńlá àti ògo:àti òdodo Rẹ̀ dúró láéláé.

Sáàmù 111