Sáàmù 110:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Àwọn ènìyàn Rẹ jẹ́ ọ̀rẹ́ àtinúwání ọjọ́ ìjáde ogun Rẹ, nínú ẹwà mímọ́,láti inú òwúrọ̀ wá ìwọ ni ìrì ẹwà Rẹ.

4. Olúwa ti búra, kò sí ní yí ọkàn padà pé,ìwọ ní àlúfà títí láé, titẹ̀ àpẹẹrẹ Melekisédékì.

5. Olúwa ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹ̀ niyóò lu àwọn ọba bolẹ̀ ni ọjọ́ ìbínú Rẹ̀

Sáàmù 110