Sáàmù 11:6-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Sí orí àwọn ènìyàn búburú ni yóò rọ̀jòẹ̀yín iná àti ìmí ọjọ́ tí ń jó;àti ìjì gbígbóná ní yóò jẹ ìpín wọn.

7. Nítorí olódodo ní Olúwa,o fẹ́ràn òdodo;ẹni ìdúróṣinṣin yóò sì rí i.

Sáàmù 11