Sáàmù 109:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Eékún mi di aláìlera nítorí ààwẹ̀ gbígbàẹran ara mi sì gbẹ nítorí àìlera mi.

Sáàmù 109

Sáàmù 109:16-31