Sáàmù 109:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni èrè àwọn ọ̀ta mi làti ọwọ́ Olúwa wá;àti ti àwọn tí ń sọ̀rọ̀ ibi sí ọ̀kàn mi.

Sáàmù 109

Sáàmù 109:16-24