Sáàmù 108:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọlọ́run, ọkàn mi dúró ṣinṣinèmi ó máa kọrin, èmi o máa fi ọkàn mi kọrin

2. Jí ohun èlò orin àti háápùèmi ó jí ní kùtùkùtù

3. Èmi ó yìn ọ, Ọlọ́run nínú àwọn orílẹ̀ èdèèmi o kọrin Rẹ nínú àwọn ènìyàn

Sáàmù 108