Sáàmù 106:23-27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

23. Bẹ́ẹ̀ ní, ó sọ wí pé oun yóò pa wọ́n runbí kò ba ṣe tí Mósè, tí ó yàn,tí ó dúró níwájú ẹ̀yà náàtí ó pa ìbínú Rẹ̀ mọ́ láti má pa wọ́n run mọ́

24. Nígbà náà, wọn kẹ́gàn ilẹ̀ dídára náàwọn kò gba ilérí Rẹ̀ gbọ́.

25. Wọn ń kùn nínú àgọ́ wọnwọn kò sì gbọ́ràn sí Olúwa.

26. Bẹ́ẹ̀ ni ó gbé ọwọ́ Rẹ̀ sókè sí wọnkí òun le jẹ́ kí wọn ṣubú nínú ihà,

27. Láti jẹ́ kí àwọn ọmọ Rẹ̀ ṣubú lára orílẹ̀ èdèláti fọ́nu wọn káàkiri lórí ilẹ̀.

Sáàmù 106