Sáàmù 106:20-23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. Wọn pa ògo wọn dàsí àwòrán màlúù, tí ń jẹ koríko.

21. Wọ́n gbàgbé Ọlọ́run, ẹni tí í gbàwọ́nẹni tí ó ti ṣe ohun ńlá fún Éjíbítì,

22. Iṣẹ́ ìyanu ní ilẹ̀ Ámùàti ohun ẹ̀rù ni ẹ̀bá òkun pupa

23. Bẹ́ẹ̀ ní, ó sọ wí pé oun yóò pa wọ́n runbí kò ba ṣe tí Mósè, tí ó yàn,tí ó dúró níwájú ẹ̀yà náàtí ó pa ìbínú Rẹ̀ mọ́ láti má pa wọ́n run mọ́

Sáàmù 106