Sáàmù 105:44-45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

44. Ó fún wọn ní ilẹ̀ ìní náà,wọn sì jogún iṣẹ́ àwọn ènìyàn náà,

45. Kí wọn kí ó le máa pa àṣẹ Rẹ̀ mọ́kí wọn kí ó le kíyèsí òfin Rẹ̀.Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.

Sáàmù 105