Sáàmù 104:34-35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

34. Jẹ́ kí ẹ̀kọ́ mi kí ó tẹ ọ lọ́rùnbí mo tí ń yọ̀ nínú Olúwa.

35. Ṣùgbọ́n kí ẹlẹ́sẹ̀ kúrò láyékí ènìyàn búburú má sì sí mọ́.Yin Olúwa, ìwọ ọkàn mi.Yin Olúwa.

Sáàmù 104