Sáàmù 104:30-32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

30. Nígbà tí ìwọ rán ẹ̀mí Rẹ,ní a dá wọn,ìwọ sì tún ojú ayé ṣe.

31. Jẹ́ kí ògo Olúwa wà pẹ́ títí láé;kí inú Olúwa kí ó dùn ní ti iṣẹ́ Rẹ̀

32. Ẹni tí ó wo ayé, tí ó sì wárìrì,ẹni tí ó fọwọ́ tọ́ àwọn òkè, tí wọ́n yọ èéfín.

Sáàmù 104