Sáàmù 104:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọtí wáìnì tí ó ń mú ọkàn ènìyàn yọ̀,òróró láti mú ojú Rẹ̀ tan,àti àkàrà láti ra ọkàn Rẹ̀ padà.

Sáàmù 104

Sáàmù 104:12-20