Sáàmù 102:11-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Ọjọ́ mi dàbí òjìji àṣálẹ́èmi sì rọ bí koríko

12. Ṣùgbọ́n ìwọ, Olúwa, ni yóò dúró láéláé;ìrántí Rẹ láti ìran dé ìran.

13. Ìwọ ó dìde ìwọ o sì ṣàánú fún Síónì,nítorí ìgbà àti ṣe ojú rere sí i;àkókò náà ti dé.

Sáàmù 102