Sáàmù 10:15-17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Ṣẹ́ apá àwọn ènìyàn búburú àti ènìyàn ibi;pèé láti wa sírò fún iwà ìkà Rẹ̀tí a kò le è rí.

16. Olúwa ń jọba láé àti láéláé;àwọn orílẹ̀ èdè yóò ti ilẹ̀ Rẹ̀ ṣègbé.

17. Ìwọ́ gbọ, Olúwa, ìfẹ́ àwọn tí a ni lára;Ìwọ gbà wọ́n níyànjú, ó sì gbọ́ ìgbe wọn,

Sáàmù 10