Rúùtù 4:20-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. Ámínádábù ni baba Násónì,Násónì ni baba Sálímónì,

21. Sálímónì ni baba Bóásì,Bóásì ni baba Óbédì,

22. Óbédì ní baba Jésè,Jésè ni baba Dáfídì.

Rúùtù 4