Rúùtù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe nígbà tí ọkùnrin náà tají ní àárin òru, ẹ̀rú bàá, ó sì yí ara padà, ó sì ṣàkíyèsí obìnrin kan tí ó sùn sí ibi ẹsẹ̀ rẹ̀.

Rúùtù 3

Rúùtù 3:2-9