Rúùtù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìránṣẹ́ tí ó jẹ́ olórí àwọn olùkórè náà sì fèsì pé, “Ọ̀dọ́mọbìnrin ará Móábù tí ó tẹ̀lé Náómì wá láti ilẹ̀ Móábù ni.

Rúùtù 2

Rúùtù 2:1-11