Rúùtù 1:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nibi tí o bá kú sí ni èmi yóò kú sí, níbẹ̀ ni wọn yóò sì sin mí sí. Kí Olúwa jẹ mí ní ìyà tí ó lágbára, bí ohunkóhun bí kò ṣe ikú bá yà wá.”

Rúùtù 1

Rúùtù 1:15-22