Rúùtù 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Náómì wí pé, “Wòó, arábìnrin rẹ ti padà lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn rẹ̀ àti òrìṣà rẹ̀, ìwọ náà padà pẹ̀lú rẹ̀.”

Rúùtù 1

Rúùtù 1:7-16