Róòmù 7:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi mọ̀ dájú pé kò sí ohun tí ó dára kan tí ń gbé inú mi, àní, nínú ara ẹ̀ṣẹ mi. Èmi fẹ́ se èyí tí ó dára, ṣùgbọ́n kò sé é ṣe.

Róòmù 7

Róòmù 7:17-22