Róòmù 6:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ikú ni èrè ẹ̀ṣẹ̀, ṣùgbọ́n ẹ̀bùn Ọlọ́run ni ìyè àìnípẹ̀kun nípaṣẹ̀ Jésù Kírísítì Olúwa wa.

Róòmù 6

Róòmù 6:15-23